Thursday 7 September 2017

" LAI SI IGBAGBO A KO LE WU OLORUN"- PROPHET EPAPHRAS ODEKUNLE OF COMFORT LIFE MISSION INTERNATIONAL, OPPOSITE WEMA BANK TEMIDIRE MARKET GBAGI TITUN IBADA, OYO STATE.

 This is the detail of the exclusive interview we had with Prophet Odekunle Epaphras of Comfort Life Mission International, Gbagi Titun Area Opposite Wema Bank Ibadan, which we had said to be run in the Yoruba language it was conducted, with the clarification that our decision to publish the interview in the language we are bent to run it has nothing to do with any short-comings neither on the part of our guest nor the editorial of the News track-Online,therefore here we unwind as thus  below: 

 Wooli wa,nje e le so oruko eni ti a n ba ni iforojomitooro oro pelu ?

 Emi Wooli Odekunle Epaphras ti ile ijosin Comfort Life Mission International,ijo ti baba mi gbe kale si Oja Temidire legbe Wema Bank ,Gbagi Titun Ibadan.

 Wooli wa, ona wo le le tumo adura si,ati wipe kini itumo adura ni pato ?

 E se ,nkan eyo kan ni emi kan an maa so ni wipe,ko si itumo kii tumo ti enikeeni le tumo adura sii,eyi ti a ko baa ti ri ninu bibeli emi ko ni fowo kan , bibeli so nkan kan ninu Jeremiah 33:3 " Ke pe mi; emi o sii gbo, emi o sii fi ohun nla to lagbara te'ni kankan ko moo han o", Adura ti a nso yii ko ni apejuwe paatoo, eni baa gba adura ti adura gba fun un; lo moo adura gbaa,lo sii ko ere apejuwe itumo adura, bienikan koba tii gba'dura koo gbaa;ko tii mo itumo adura, asiri to n bee ninu adura naa niyen,ona meta waa ni adura fii n gba, nitori pe awa koo laa n dahun adura; olorun lo n dahun adura ,o sii ni ona meta kan an to'lorun fi n dahun adura: alakoko ni wipe eniyan le gbadura leeni; ko sii yaa ni kiakia,eyi ni a npe ni 'automatic-prayer' fun 'automatic-anwer',eleekeji ni wipe eniyan lee gba adura ki olorun si sowipe kii eniyan ni suuru; mi o tii setan ti n see,ko sii eni ti o lee mu olorun sii,lo fi n je 'kabiyeesi';ka bii ko sii. Eleekeeta ni wipe olorun so wipe mio nii see, se ohun ti oo baa maa see,meteetaa yii naa lo sii waa ninu bibeli, awonj kan an gbadura; loju ese bii won se kunle bayii ti won gbadura ni 'automatic-anwer' dahun; iru won nii Bartholomew afoju,bo see kunle to pee bayii wipe " Jesu Omo Davidii saanu mi" loju ese olorun sii da lohun. Iyen nikan koo, awon kan si wa to'lorun so fun wipe ni suuru si adura won bii Abraham,igba to to wo ogorun odun ti iyawo wo ogorun o din mokanla niolorun too da won lohun,ko fun won titi ayafi igba ti won too wo ojo ogbowon kii olorun to fun won lomo; Isaki, ayafi igba ti Hannah to woo ogota odun kii olorun too daa lohun,iyen nikan koo, awon kan sii waa ti olorun so pe ohun ko nii see; iru won nii Paul o nii "eemeeta ni mo gbe oju mii soke sii o ,mu eegun yii kuro lara mii", olorun sii soo pee "ma wule gbadura; oore ofe mi to fun o,nko nii see", Moses so fun olorun pee " je kii n de ile-ileri"; a mo olorun so fun un pee "n ko nii see",ohun to je kii n daruko awon wonyii nii wipe eniyan mewa lo wa ninu bibeli to je aladura,ti olorun baa gbaadura won, o too bee,iru won ni Moses, gbogbo adura re lo gbaa, ayafi adura to gba lati de ile-ileri,Olorun ni "O ti naa mii,o tii doju timi nii gbangba,eyi naa nii emi naa ko nigbo",owa mu lo si ori-oke Pistag o nii " woo gbogbo iwaju ree yii to je ile-ileri,sugbono ko ni dee bee oo",igba to tun gba adura leekeerin,olorun soo fun pee "maa paa o, ti o ba tun beere lati dee ile-ileri lowomii".

 Wooli wa! 'korensi'ti a n naa ni Nigeria Naira nii, ni America dollar nii, ni ilu Oba binrin oyinbo pound-sterling nii, awon kan sope 'korensi'ti a n naa ninu adura gbigba pe e 'igbagbo' ni, kini e le so lori eyi ?

 Ko si ohun ti e le lee gba lai sii igbagbo,biobeli sopee " lai sii igbagbo a ko lee wuu olorun ",kii see 'anointing' to wa lori wooli lo nii se nipa gbigba adura;bii ko see igbagbo eni ti a n gba adura fun un tabi ti o n gba adura, ohun to n tuu eda sile nii igbagbo ti enikeni baa nii ninu adurare, bii 'anointing' baa n san an lori wooli ,tii n gbadura ti ina lojukoroju ba n yo; ti eni to n gbadurafun un ko baa ni igbagbo lati ibi yii dee ibe yen;ko si ohun ti yoo sele,ohun lo faa ti Jesu fii kuro ninu ilu ree, won nii " ko sii lee see ohun kankan pupo, nitori aini igbagbo won",kini won n pe ni igbagbo Iwe Hebrew 11:1 " Idaniloju ohun ti a n reti , ijeri ohun ti a ko rii ". Bi igbagbo baa waa ninu aye eniyan , ninu isoro sii ree ni e o ti moo , obinrin onisun eje wipe " bi emi baa lee fowo kan iseti aso ree; ara mii yoo sii yaa gaga ", o ti koko gba gboo , eyi ni oro pataki to dara pupo ninu oro ree,eleekeji ni ninu ihuwa sii ree won so wipe o dide o sii n loo sii odo ree (Jesu).
 Bo ti le je pe won gba sibi sohun, siwa segbe, a mo o ri pe ohun dodo Jesu, lati fo'wo kan eti aso ree, eniyan ko ni joko sile ko ni ohun ni gbagbo, bibeli ni "laalaa awon asiwere nda olukuluku won laa mu-Iwe Oniwaasu10:15 toripe won ko mo bii won se n jade lo sinu ilu", eyi maa n da ni laamu, nitori pe igbagbo yen ko ni sise, igbagbo je ohun to ma a n tini sise (moving-force), faith would move you .

Ijo n po si ese n po si i, kilo faa?

Asotele Jesu ni, ko si si eni to le yii pada, ese ko ti i po, o ku die, bibeli so ni Matthew 24verse12 "Ese yo o di i pupo, ife opolopo yo o di i tutu  "asiko nbo nigba ti Jesu yoo ba a fi i de e, amin opin aaye ni, ese yoo po de ibi pe e won yo o ma a mu u bi eni pe e won n mu bata lori igba ni i, Pasito gan an gan an yo o ma a mu u siga lori i altar ni i, ese ko ti i de e, ese mbo, o ku u tintin ni, se a sese ngbo pe e omo odun maarun ati omo odun mejilelogun nse igbeyawo n i, eyi to le ju u be e lo o mbo.

Awon elesin alagbere to n lo lati ijo kan lo sibi kan; ki lo fa a ati wipe ki le e ri i si i?

Ki lo nje elesin-alagbere, awon kan lo o nso  be e, ko si i ohun to nje be e, ko si i ijo lorun, emi ni Comfort Life, Deeper Life, emi ni kini kan igba ti a ba de ijoba oorun, ko si gbogbo iyen nibe, eni ti o ba a fa aye re fun un Jesu; to si ngbe igbe aye mimo ni yo o la a, nitori na a gbogbo eyi ti won so pe enikan n sa a lo o si i ijo kan, awa wi i ni i, emi a ma a so ninu ijo wa pe ti ijo yi i ko ba a mu o yato, ya a ye'ra fun un.

Idile Musulumi le ti i jade wa, musulumi lo si i bi i yin in, bawo wa a le se e do ni gbagbo?

Ko da ki i se pe Musulumi lasan ni mi i, mo tun lo si i ile keu omo Sawia, ojo kan ni mo ba Jesu pade, buoda mi lo mu mi lo o si ile-isin onigbagbo, won waasuu fun mi nipa orun apaadi, won si ni bi mo ba a fe e bo ki n te le awon lo, igba ti a de ile-ijosin yi i ni mo o ba a be e, gbogbo ohun ti won ka a jade ninu bibeli lo o ri i be e, n ko tile lero pe olorun le pe mi orun apaadi ni mo sa fun.

 Wooli ati Pasito, kini itumo mejeeji ati ise won?

E se, meji yi i ko, maarun ni won; a ni Apositeli, Wooli, Efanjelisi, Tisa ati Pasito, maarun yi i la ni, gbogbo ijo ti e ba a ri i, awon maarun ni olorun gbe akoso ijo le lowo, a mo ise won yato, bibeeli so ni Act 12 pe e " Orisirisi ise lo wa a, sugbon emi kana an na a ni", eni ti won npe ni Apositeli , ko le e se ise wool, o kan je pe awon wooli abami eda ni won, won a ma a so aditu ( they speak mysteries), won a maa so ijinle ( they speak the deeps), sugbon maraarun ni Jesu ti i sise, ma a wa a mu ibi to ti sise bi i wooli se akawe; bibeeli so pe okunrin kan wa to fo'ju (Batholomew) bi Jesu ti i pade e re ; o si i tu ito sile, o si i po o mo potopoto, o si i re e mo o loju, o ni ko lo o fo o lodo, bo ba se aaye ti a wa yi i ni enikan se iru eyi; babalaawo ni won yo o pe e. Ekeji; ojo kan o de e eti kanga lo ba a pade obinrin kann nibe; o si i beere si i so o asiri fun un, a mo awon wooli si i iran ati asotele, eyi ti a mo Jesu fun un bi i wooli. O so fun un awon omo lehin re e pe e ese yoo di i pupo, e waa wo o bi i ese se n po o si i ninu aye bayi.
 Bi Jesu se so fun awon asiri yi i fun obinrin yi i ni obinrin yi i bere lowo Jesu pe e " wooli ni o bi i", o si i da lohun pe e  " eni ti o ju wooli lo ni mi". Nitori naa Jesu se ise ihinrere re e bi Apositeli, Wooli, Efanjelisi, Pasito ati Tisa, lo je ki i a  ma a pe Jesu ni Raabi, eyi ti o n je oluko lona miran, o si tun se ise bi i Efanjelisi.

Igba ti e gba Jesu, awon idojuko wo le ri i?

Aah!, o po gan an ni, baba mi Musulumi ni, ni kete ti a gba Jesu, ti a ko fe lo si ile-keu mo a je pasapasa iya, ni tooto mo ka ninu bibeeli wipe eni ti yoo gbe igbesi aye bi i Jesu yo o fara da inunibini, won ko fun wa lowo ounje mo, won da wa si odo mama wa, ohun nikan ni o nse itoju wa, nigba ti baba wa yo o fi ku a sise to o to fi gba Jesu ni i, a je iya o, a je iya.

Kini idi ti won fi i n pe ijo yin in ni 'olorun-ojiji' ?

Comfort Life Mission International ni oruko ile-ijosin yi i aka Champion-Chapel, mo se isin ita gbangba kan ri ni ori i-papa Iyemetu Baraki nigba kan ti mo pe ni 'Olorun-Ojiji', Oyinbo gan an ni mo o ko, sugbon nigba ti awon eniyan de e, awon to gbno ede yoruba lo po nibe; a wa tumo re e si i 'olorun-ojiji',igba ti a se e isin yen tan an ni ohun ti a ko fokan si i sele, lojo ti a wi yi i; ibe ni mo ti ri oju afoju to la a lai gbe owo mi le e, n ko mo bi o se e sele, owo mi ko kan an, o kan an sa a gba iwosan ati imularada ni i, ti oju re e si i la a , iyen nikan ko o; omode kekere kan ti oruko re e nje Dasola, obinrin ni,Dasola ko le fo ohun, odi ni i, lehin ti a pari isin yi i tan an lo ba a n soro, ni awon eniyan ba a wa a so o pe ki a kuku ma a se isin yi i leralera, a se leekini, leekeji, leeketa, leekerin, bo se di eekan na a nigba ti a de ibi yi i ni won ba bere si i pe wa ni 'olorun-ojiji ', mo wa a wo o bi eniyan ba ye e wo o ninu bibeeli gan an na a , bi eniyan ba a si i le e ri i olorun gan an naa; a je pe ki i se e olorun mo niyen, ohun meeji ni eyi i ma a n mu wa a ranti ; a n ranti pe e ojiji ni Jesu yo o de e lojo kan, Jesu so pe " emi nbo bi i ole loru", gbogbo igba ki i gba ti won ba a ti i daruko olorun-ojiji ni o ma a nje ki i n mo wipe Jesu ma a nbo lojiji lojo kan, ati wipe ko si i eni to le e so asotele ojo ti i yo o ku u, ti iku yo o de e si i eniyan, iyen ba un, ojo ti olorun yo o Paul ati Saila ninu tuubu Iwe ise awon omolehin Jesu (Act of Apostle) so wipe " Won si i n yin olorun lojiji, lojiji ni afefe nla si i de e, mimi si mi i, ile tuubu si mi i", nitori eleyi mo le e se akawe lorisisrisi ibi ti olorun ti yo o si awon eniyan re lorisirisi, o yo o si i Obedeodom lojiji, o ti i fe e ku u tele ni won ba a gbe apoti eeri de e lojiji si i ile re fun ayipada rere.
BAYI NI A MU OPIN WA A SI ITAKUROSO PELU WOOLI ODEKUNLE EPAPHRAS TI ILE-IJOSIN COMFORT LIFE MISSION INTERNATIONAL, TI O FI I IKALE SI I OPOPONA NEW IFE ROAD OJA-GBAGI TITUN, LEGBEE WEMA BANK NI IBADAN.

 N.B:-Meanwhile we hereby tender our apology for the delay in the exclusive interview we had with the President of Nigeria Union of Local Government Employees,NULGE Oyo State Chapter; Comrade Bayo Titilola Sodo while we promised that it would be the next publication after this, thanks for your usual cooperation.



   




No comments:

Post a Comment